Skip to content
Video

Àṣà Ìlà Kíkọ nínú Ìtàn Yorùbá

Description

Àṣà Ìlà Kíkọ nínú Ìtàn Yorùbá; jọ̀wọ́ ẹ̀ bá wa wo ìtàn pátápátá tí ó wà lẹ́yìn ìlà kíkọ nínú àṣà Yorùbá. Àṣà yìí ti jẹ́ àpá kan nínú ìdájọ́ ẹ̀wà àti ìdámọ̀ àwọn eèyan ní ilé Yorùbá. Ṣùgbọ́n, báwo ni a ṣe ń wo ọ́ lónìí? Ṣé ó tún ṣàkóso bí ti ìgbà àtijọ́? Kọ́ nípa ìdí tí àwọn ènìyàn fi ń ṣe ìlà kíkọ, àwọn oríṣìíríṣìí ìlà tó wà, àti bí àṣà yìí ṣe ń yí padà lónìí. Má gbàgbé láti ṣàbẹ̀wò, tẹ Like, Comment, àti Subscribe!